A ó ma fi àwọn fọ́nrán sí orí ẹ̀rọ yìí ní ojoojúmọ́ fún idanilekoo fún àwọn èwe àti ìrántí ìgbà èwe wa.